MONIQUE Ride On cover image

Ride On Lyrics

Ride On Lyrics by MONIQUE


[VERSE 1]
Agbára Olórun mbe níbí
The Power of GOD is here
Èmí Olórun mbe níbí
The Spirit of GOD is here

[CHORUS]
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn
Momòpé bímobá képè é, Á sògo
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí oooo
Ride On, Ride On, Ride On

(Agbára Olórun mbe níbí
The Power of GOD is here
Èmí Olórun mbe níbí
The Spirit of GOD is here

Momòpé bímobá képè é, Óma foùn
Momòpé bímobá képè é, Á sògo
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí oooo
Ride On, Ride On, Ride On)

[VERSE 2]
Let my ears belong to you
So all i hear is you
Let my heart belong to you
So all i do is you
Shield me from the power of sin
Let them gat nothing on me
Holy Spirit, gbàmí tán

[CHORUS]
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn
Momòpé bímobá képè é, Á sògo
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí oooo
Ride On, Ride On, Ride On

Agbára Olórun mbe láyé mi
Agbára tóh borí ohun gbogbo
Who art thou oh mountain níwájú Oba gbogbo ayé
Olúwa tóh pò nípá àti agbára
Òkan soso òrò tí nso gbogbo òrò
Òrò gbénú omi adágún
Òrò gbénú omi òkun ru
Ìjìnlè nlá Atófaratì bí òkè
Mopá tàsetàse L’órúko JÉSÙ Kristì
Egbé oríiyín sókè
Eyin enu ònà, kí asì gbé e yín sókè èyin ilèkùn ayérayé
kí Oba ògo kíó wolé wá
Àkóbí nú àwon òkú, òdó àgùntàn tíó fèmí rè lé’lè fún wa
Olùdámòràn, igi òkìkí, àpáta aìí dìgbòlù, òkè táò l’esí
Òjìjí àti ìmólè


About Ride On

Album : Ride On (Album)
Release Year : 2020
Added By : Farida
Published : Mar 19 , 2020

More MONIQUE Lyrics

Comments ( 0 )

No Comment yetAbout AfrikaLyrics

Afrika Lyrics is the most diverse collection of African song lyrics and translations. Afrika Lyrics provides music lyrics from over 30 African countries and lyrics translations from over 10 African Languages into English and French

Follow Afrika Lyrics

© 2022, We Tell Africa Group Sarl