...

Paroles de Adura Mi Par TOPE ALABI


Eyi nikan

L'adura mi

Si Olu Aseda mi

Eyi nikan

L'adura mi

Mo ti mo ona iye yi na

Mi o ni yese

Mi o ni pada

Emi o ni si lo

Kododo aye ma fe mo oju mi

Ju ibi t'ayo mi wa lo

Amin Amin Amin

O Amin

Eyi nikan le mi nbere

Nigba ti mo n mi

Ko na t'oluwa mu mi rin yi o

K'emi ma se amoju sonu

Kin le d'ebute ogo ayanmo

Kogo baba ko tan de opin

Imole ko tan de opin aye

Fun oruko re nikan

O Amin

(O Amin

O Amin

O Amin

O Amin)

Eyi l'ohun temi n bere

Anu ati abo re

Owo re at'otito re

Ko tan mi l'aye d'ogbo

Ani ko se Asa at'Apata

Ko ma yo wo ni pe ja mi

Eni sare ibi le mi

Ko f'ori ara re gbe

Gbe'be mi s'ase

O Amin

(O Amin

O Amin

O Amin

O Amin

O Amin)

Eyi l'ohun temi n bere

Awon omo to fun mi

Ki won sin o

Iwo nikan

Ki won ko se rere laye

K'alaafia ati ife re

Ma joba ni ile wa

Opopona majemu ayeraye

Ni ka wa o fo titi

Alaafia ogbo tutu

Ni ipin tawa lodo aseda

Beeni ko ri oo

(O Amin

O Amin

O Amin

O Amin)

Eyi nikan l'adura mi

Owo oluwa ko kun mi pupo

Ki ina mi jo fun isoji si

Labe asiapada bo re

Ka sa ko pada l'ohun kan

Kero ijoba re ko po si

To ba si de oko iyawo

Awa yo ba o joba

Adura mi ni

Ko se oo

O se O se

(O Amin

O Amin

O Amin

O Amin)

Adura mi ma ti gba (Baba mi a gbo)

Ohun ti emi bere (Baba ti se oo)

Ogede ki n gb'odo ko ya gan beeni (Baba mi a gbo)

Elegbede f'owo lu'gi o dun jaye oo (Baba ti se oo)

Omo o le bere akara ka fun lo kuta oo (Baba mi a gbo)

Igbagbo ninu Jesu kin doju tini (Baba ti se o)

Ohun gangan ti mo n bere (Baba mi a gbo)

Ati iran de ran mi Olorun la o ma sin titi (Baba ti se o)

Ke mi o mo fo ojo aye mi si Oluwa (Baba mi a gbo)

Oore ofe ati iferan Olugbala mi si (Baba ti se o)

Kin ma joko l'ese re nigba gbogbo ko eko oo (Baba mi a gbo)

K'emi se yi di ojo ogbo tutu ni mo bere oo (Baba ti se o)

Iran peregun won ki rin wowo kin ku dale (beeni) (Baba mi a gbo)

Ka le wa san mi ju owuro lo Olu nla mo be o (Baba ti se o)

Eeeh Amin

(O Amin

O Amin

O Amin

O Amin)

Ase

Amin

Ase o

Ema s'amin ase

Amin

Amin

Ase

Ecouter

A Propos de "Adura Mi"

Album : (Single)
Année de Sortie : 2025
Copyright :
Ajouté par : Farida
Published : Apr 23 , 2025

Plus de Lyrics de TOPE ALABI

TOPE ALABI
TOPE ALABI

Commentaires ( 0 )

Aucun commentaire pour l'instant



A propos de AfrikaLyrics

Afrika Lyrics est la plus large collection de paroles de chansons et de traductions d’Afrique. Afrika Lyrics fournit les paroles des musiques de plus de 30 pays africains et des traductions de lyrics de plus de 10 langues africaines en français et en anglais.

Suivre Afrika Lyrics

© 2025, We Tell Africa Group Sarl