
Paroles de See Me See God
...
Paroles de See Me See God Par BARRY JHAY
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j'alangba tutu a farapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
iku mama pa awọn to gbe mi sori bi gele
Ki ibanjẹ jina si wa rere tefe tefe
Ki iku maa p'ọta mi, ko le riran wo
Ki iku maa p'ọta mi, ko le riran wo
(Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo
Ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one
Motivation gan-an ti n payan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ
(ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy ye ye eeh
Ṣhey you dey see level o
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ
As I dey find wetin I go chop, ooh
Make I no jam wetin go chop me
Oluwa lo gbe lo gbe mi soke
Emi ko le ṣa i ṣọpẹ
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy ye ye eeh
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, o loju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one
Motivation gan-an ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ
(ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle bo ye ye eeh
Ṣe you dey see level o
Ecouter
A Propos de "See Me See God"
Plus de Lyrics de BARRY JHAY
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl