TOPE ALABI Logan Ti Ode cover image

Paroles de Logan Ti Ode

Paroles de Logan Ti Ode Par TOPE ALABI



Emi mo oun oju mi tiri
Mo mo oun eti mi ti gbo
Mo oun oju mi tiri
Mo mo oun eti mi ti gbo
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala
Aiye mi le to
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala
Aiye mi le to

Mo mo oun aiye ma ti wi
Mo mo oun eyan ma ti so
Won ti pe wa ni agan ri
Boya won ti pewa lo’olosi ri
Sugbon, logan ti o de o Olugbala, laye mi le to
Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to

Aye to ti daru tele tele o
(logan ti o de)
Oro ti eniyan ti fi s’alufani re
(logan ti o de )
Oro ti ko dara ta ti so si o
(logan ti o de )
Oruko ti kin se tire ta ti pe o
(logan ti o de )
Ani logan ti o de o Olugbala aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Logan ti Jesu de o Olugbala, l’aye e le to

Ko s’oruko t’aye o le pe ni
wa ma peni l’agan l’ona gbo gbo
Bo ba lowo lowo agan ni, bo ba bi mo o agan ni
Bo ba tegba ko dagba agan lo je
sugbon logan ti o de, sope logan ti o de
Ani logan ti o de, lesekese, logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to
Instantly lo’n je be
bo se n debe, won de yi oruko pada

Logan ti o de, eheheh logan ti o de
eyin ta pe l’agan e ma so wi pe, logan ti o de
Awon ta ti fi oruko aburu pe ni’le won yi
(logan ti o de )
Ani logan ti o de o Olugbala,( l’aye mi le to )
Logan ti o de o Olugbala, (l’aye mi le to )
Ani eheh, logan ti o de o Olugbala, (l’aye mi le to )
Ani, logan ti o de o aseda, (l’aye mi le to )
Ani, logan ti o de o Olorun o, (l’aye mi le to )
Irawo owuro omo
ary yo sinu oro mi, (l’aye mi le to)
Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere,( l’aye mi le to)
Enu mi wa kun fu eri o gbogbo,( l’aye mi le to)
Aye mi gba iyipada otun o logan to de,( l’aye mi le to)
Aye mi ba leto l’ota ba wo Iran mi, (l’aye mi le to)
Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, (l’aye mi le to)
Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, (l’aye mi le to)
Ahah, logan ti o de o Olugbala,( l’aye mi le to)

Thank you Lord Jesus for all that you are

Ecouter

A Propos de "Logan Ti Ode"

Album : Logan Ti Ode (Single)
Année de Sortie : 2018
Ajouté par : Preslie Nzobou
Published : Feb 19 , 2020

Plus de Lyrics de TOPE ALABI

TOPE ALABI

Commentaires ( 0 )

Aucun commentaire pour l'instant



A propos de AfrikaLyrics

Afrika Lyrics est la plus large collection de paroles de chansons et de traductions d’Afrique. Afrika Lyrics fournit les paroles des musiques de plus de 30 pays africains et des traductions de lyrics de plus de 10 langues africaines en français et en anglais.

Suivre Afrika Lyrics

© 2025, We Tell Africa Group Sarl