
Pawo Lyrics
...
Pawo Lyrics by BHADBOI OML
Pawo
Pawo
Ma jẹ gbese
Pawo
I no dey grind to work 9 to 5
I was made to swim in a turquoise red
I no dey grind to work 9 to 5
I no hear tupatu papatupa
Onimiliki o ya were
Alagolo lo n sinwi
Onimiliki o ṣiere
Alagolo lo n sinwi
Woos
Wo nigga to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe o ti jẹ bo ṣe ma jẹ
Ọmọ to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe fọga lo ṣi ma fẹ
Cause ẹ le f'emi kọrọsọ
Ẹ le f'emi kọrọsọ
Cybertruck mo ba rode
My money no go kala
Wo nigga to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe o ti jẹ bo ṣe ma jẹ
Ọmọ to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe fọga lo ṣi ma fẹ
Cause ẹ le f'emi kọrọsọ
Ẹ le f'emi kọrọsọ
Cybertruck mo ba rode
My money no go kala
When I step in the room, all the ladies shout oblee
(O le f'emi we awọn kan)
Mo lowo lapo, now I just dey find opueh
(Body don dey find ọmọ)
Oh baby so demure
Mo ti mọ pe money lo ṣi ma fẹ
Ọmọ to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe Jigan lo ṣi ma fẹ
Ice on my wrist, I'm cold
A she party wọn fo
Alakọri ni wọn o
Oje ni wọn lo
Onimiliki o ya were (Ey)
Alagolo lo n sinwi
Onimiliki o ṣiere (Ey)
Alagolo lo n sinwi
Woos
Wo nigga to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe o ti jẹ bo ṣe ma jẹ
Ọmọ to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe fọga lo ṣi ma fẹ
Cause ẹ le f'emi kọrọsọ
Ẹ le f'emi kọrọsọ
Cybertruck mo ba rode
My money no go kala
Wo nigga to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe o ti jẹ bo ṣe ma jẹ
Ọmọ to fi mi lẹ
Mo ti mọ pe fọga lo ṣi ma fẹ
Cause ẹ le f'emi kọrọsọ
Ẹ le f'emi kọrọsọ
Cybertruck mo ba rode
My money no go kala
Watch Video
About Pawo
More BHADBOI OML Lyrics
Comments ( 0 )
No Comment yet
You May also Like
Get Afrika Lyrics Mobile App
About AfrikaLyrics
Follow Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl