
Burn Fire Lyrics
...
Burn Fire Lyrics by BHADBOI OML
Aah
Agba n tara, abetilujere bi ajere
Alligator pepper na atare
Abetilujere bi ajere
Aah Agba n tara
Firstly ma dupẹ lọwọ maker mi
Ogogoro no kolombi o maker mi
Na ojoro kolombi your picker
My padi, my padi
Iṣẹ wo lo n lọ, my padi
To rowo lo n jẹ my darling
To rowo lo n jẹ my darling
My padi, my padi
Iṣẹ wo lo n lọ, my padi
Change topic, what's popping
Change topic, ace popping
Don Dada, Don Don Dada
Ogo Idi Oro burn burn fire
Kini mo ṣe, kini mo ṣe
T'ọn, t'ọn para
Kini mo sọ, kini mo sọ
T'ọn, t'ọn para
Don Dada, Don Don Dada
Ogo Idi-Oro burn burn fire
Kini mo ṣe, kini mo ṣe
T'ọn, t'ọn para
Kini mo sọ, kini mo sọ
T'ọn, t'ọn para
Wahala, wahala, wahala, wahala, wahala
Ọmọ see palava (Ọmọ see palava)
Wọn bo ko lọ far (Wọn bo ko lọ far)
Wahala, wahala, wahala, wahala, wahala, wahala
Ọmọ see palava (Ọmọ see palava)
Wọn bo ko lọ far (Wọn bo ko lọ far)
Aah
Agba n tara, abetilukẹrẹ apocalypto
O fa agbara yọ, abido shaker
Abetilukẹrẹ apocalypto
Onitibi lo ka mi mọle
O ba mi lalejo
Ko wọ pata, ko wọ kọmu wa, Agbani Darego
Personal o connect mi ti o cava
Bonjour lomase olo mi commot cava
Ọmọ waka waka o n ṣe bi ajẹbutter
To ṣi ma bọ pata tan patapata
You should already know me
You should know me better
You should already know me
You should know me better
Firstly Ma dupẹ lọwọ
Fir Firstly ma dupẹ lọwọ maker mi
Ogogoro no kolombi o maker mi
Na ojoro kolombi your picker
My padi, my padi
Iṣẹ wo lo n lọ, my padi
To rowo lo n jẹ my darling
To rowo lo n jẹ my darling
My padi, my padi
Iṣẹ wo lo n lọ, my padi
Change topic, what's popping
Change topic, ace popping
Don Dada, Don Don Dada
Ogo Idi-Oro burn burn fire
Kini mo ṣe, kini mo ṣe
T'ọn, t'ọn para
Kini mo sọ, kini mo sọ
T'ọn, t'ọn para
Don Dada, Don Don Dada
Ogo Idi-Oro burn burn fire
Kini mo ṣe, kini mo ṣe
T'ọn, t'ọn para
Kini mo sọ, kini mo sọ
T'ọn, t'ọn para
Wahala, wahala, wahala, wahala, wahala
Ọmọ see palava (Ọmọ see palava)
Wọn bo ko lọ far (Wọn bo ko lọ far)
Wahala, wahala, wahala, wahala, wahala
Ọmọ see palava (Ọmọ see palava)
Wọn bo ko lọ far (Wọn bo ko lọ far)
Watch Video
About Burn Fire
More BHADBOI OML Lyrics
Comments ( 0 )
No Comment yet
You May also Like
Get Afrika Lyrics Mobile App
About AfrikaLyrics
Follow Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl