Paroles de Oga Nla
...
Paroles de Oga Nla Par CDQ
Oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
Sego ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
MC ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Toh ba be o ma te
Swagi bi eni ti egbe ndun, buh ara ni mo fi gbe
I’ll rather be a king in the jungle, than to be a dog in the city
These niggas wanna pull me back but o shock wan I did it
Packaging lon fin disguise,
All these rappers are fish pie
No Godfather shugbon Olohun wa lori hustle yi e sure me die
Mo Kunle poly wan piu piu
Fowo komi lorun ke chill chill
Gbe keke lo bi COVID-19, mio tana webi keep distance
Oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
Sego ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
MC ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Omo igboro gon n’je
Won tin gbo lati 80’s 90’s awon genZ gon je
Awa kon fine ni stainless
Tonba gbe’mu e E’le won pelu stainless
Omo eyan kon den watch nio
Eje shebi Oluwa loni timing
Certified bars lawan bi sori mic anytime
Oluwa loni Banging
Maso pe o Gbo o maso pe o gba o
Maso pe o Gbo o Maso pe o gba o
Oganla la je anywhere jibiloa
Oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
Sego ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Bere mi ninu abete,,,, oga nla ni mo je
Lekki de mushin olosha,,, oga nla ni mo je
MC ki lo kan boss,,, oga nla ni mo je
Actor Lon shey wahala,,, oga nla ni mo je
Kini bolo Keji bolo panbolo kunbokun
Ma bo nooni Jon bo le’kan
An bo nooni Paso o
CDQ jonmo
Ecouter
A Propos de "Oga Nla"
Plus de Lyrics de CDQ
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl