
Paroles de Chocolate & Caramel
...
Paroles de Chocolate & Caramel Par BHADBOI OML
Ọrọ n gbenu mi sọrọ
Oṣa n gbenu mi fọhun
Sango n gbenu mi ṣo mọ
Ẹluku n gbenu mi fọhun
And I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta logo Benz
Pikin wey say him papa no go sleep, him mama no go vex
Many pepper no go rest
Chocolate and caramel
Obi ati orogbo
Ẹyin lẹ ma sin iya yin
Oku on sanwo posi, ṣo mọ
Chocolate and caramel
Ẹbu at'ogogoro
Ọla n bi wọn ninu
On ka wọn lara
Let's take it back to bad good days, old days those days tẹ n foribẹ
I told 'em, I told 'em, on ja mi lara jẹ buh na tip of the iceberg
Aponle diẹ, diẹ, diẹ lara n fẹ
Afọṣẹ n bẹ to ba fẹ o ma lala ri were
Ṣọpọnna ni mi mo ni kẹ ma rin mi fin
It, it is what it is, me I kuku come in peace
Kilimanjaro lẹ n sọ fun pe arara o ga
Ẹ lọ sọ fun ọga yin pe Ọmọla sọ pe "Ori wọn o da"
Wọn le, wọn le, wọn le, wọn o ba
Wa wo Ronaldinho o ma mọ pe Messi gan-an o da
And I no too like to dey vex
Ẹyin ẹlẹnu mẹta logo Benz
Pikin wey say him papa no go sleep, him mama no go vex
Many pepper no go rest
Chocolate and caramel
Obi ati orogbo
Ẹyin lẹ ma sin iya yin (Oouh weeee)
Oku on sanwo posi, ṣo mọ
Chocolate and caramel
Ẹbu atogogoro
Ọla n bi wọn ninu
On ka wọn lara
Ecouter
A Propos de "Chocolate & Caramel"
Plus de Lyrics de BHADBOI OML
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl