
Paroles de Alimanjiri
...
Paroles de Alimanjiri Par BHADBOI OML
Kar gayni wanna kolo
Kar gayni wanna wars
Aṣiri a bo
Ẹyin gan-an o ṣe bi pe mo gbọ Hausa
Asalamalaykun almajiri al selimama
Asalamalaykun almajiri al selipapa
Ṣebi you know me
Awori no dey say wetin he no mean
Ṣebi you know me
Ṣebi you know me
Ah ah ah
Bringing life Bimpe mo gbayan mi
Bringing lights to our community
I'm rocking Cuban gbọmọ lọ Cubana
Cubana for this hard economy
Iṣẹ agbe la fi n ball, almajiri al selimama
Asalamalaykun almajiri al selipapa
Fẹjọ lẹ do transfer almajiri al selimama
Bani inn barka shi neh ball almajiri al selipapa (Babiyalla)
Ẹ ye ma ba mi sọ, e ye ma ba mi sọ
Ọrọ were tẹle ba soldier sọ
Nawonawo l'emi mo emi aborogunjo
Ẹ jẹ n dele ọrẹ mi
Gbelepawo, Dapper ọrẹ mi
Baddo ọrẹ mi
Babalashe Zanku ọrẹ mi
Iṣẹ agbe la fi n ball, almajiri al selimama
Asalamalaykun almajiri al selipapa
Fẹjọ lẹ do transfer almajiri al selimama
Bani inn barka shi neh ball almajiri al selipapa
Wamuhlele wamuhlele I no send your mama o
Me wey no send your papa o
Wetin be the matter o
Me wey no get data
Bringing life Bimpe mo gbayan mi
Bringing lights to our community
I'm rocking Cuban gbọmọ lọ Cubana
Cubana for this hard economy
Iṣẹ agbe la fi n ball, almajiri al selimama
Asalamalaykun almajiri al selipapa
Fẹjọ lẹ do transfer almajiri al selimama
Bani inn barka shi neh ball almajiri al selipapa
Ẹ ye ma ba mi sọ, e ye ma ba mi sọ
Ọrọ were tẹle ba soldier sọ
Nawonawo l'emi mo emi aborogunjo
Ẹ jẹ n dele ọrẹ mi
Sokedowo Garry, ọrẹ mi
Zino ọrẹ mi
Palumbo ọrẹ mi
Fa haya ko gba wire
Iṣẹ agbe la fi n ball, almajiri al selimama
Ecouter
A Propos de "Alimanjiri"
Plus de Lyrics de BHADBOI OML
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl