
Paroles de Alade Ade
...
Paroles de Alade Ade Par BHADBOI OML
Ọmọọla leleyiiii
Listen to the sound bending
Sound bender
Alade Ade
I don't really know what to talk about you
Ija lo de lorin d'owe o
Alade Ade
I don't really know what to say about you
Ọmọ I de try Alade I de try
Ko le kol e ẹ ẹ ri po n gun ọna ọfun
Omo I de try Alade I de try
Ko le kol e ẹ ẹ ri po tough
Ma we yii oo (Mawe)
Oluwe ma we yii o (Mawe)
Ma we yii oo (Mawe)
Oluwe ma we yii oo (Mawe)
Ẹ ma wẹyin oo (Mawe)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si oo (Mawe)
Ẹ ma wẹyin oo (M we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si oo (Mawe)
Life is war, came with my ammunition
I bring sword I will never ever miss shot
Life is sure loṣhey ma n kami niṣan
Life is sure loṣhey ma n kami niṣan
Son of Adam, do you have a girlfriend
Does she give you peace
Does she give you kiss and less stress
Ṣhey ọmọ eku okin ke bi ọmọ eku
Abi ọmọ ẹran okin ke bi ọmọ ẹran
Most times, most times na money palava
Another time, most times na woman wahala
Edumare jẹ n jọba pẹ
Apẹkoto jẹun ṣi le j'ẹbajẹ
Ma we yii oo (Mawe)
Ni Mushin l'Olosha (Mawe)
Ma we yii oo (Mawe)
Lẹgbẹ shop ọrẹ mummy mii (Mawe)
Ọmọ I de try, Alade I de try
K’ole K’ole eeri p’ogun ona ofun
Omo I de try Alade I de try
K’ole K’ole eeri pe o tough
Ma we yii ooo (Mawe)
Oluwe ma we yii oo (Mawe)
Ma we yii oo (Mawe)
Oluwe ma we Yii oo (Mawe)
Alade Ade
I don’t really know what to talk about you
Ija lo de lorin d'owe oo
Alade Ade
I don’t really know what to say about you
Ẹ ma wẹyin oo (Mawe)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si oo (Ma e)
Ẹ ma wẹyin o (Ma we)
Idi ọrẹ mi ni n o fi si oo (Mawe)
Ecouter
A Propos de "Alade Ade"
Plus de Lyrics de BHADBOI OML
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl