
Paroles de Morayo
...
Paroles de Morayo Par BALLORANKING
N′Orile, orin ti de
Ojuelegba, wọn ma ṣa ẹ lẹgba
Ni Surulere, wọn o ni suru
Yeah yeah
You know say na Zero Pa
I am Balloranking
(Sh'-Sh′-Shakablaka)
Ọmọ, mo ya gbọna ti mi mọ (Ti mi mọ)
If sapa dey, I mọ pe o ni ba mi lọ (O ni ba mi lọ)
Name any hustler, dey for Babylon (For Babylon)
If I no make am, ta lo fẹ ba mi gbọ (Fẹ ba mi gbọ)
Ṣo ma jẹ ki n mọ bo dẹ ṣe ma jẹ (ṣe ma jẹ)
Ṣo ma jẹ ki n mọ bo dẹ ṣe ma jẹ (Ṣe ma jẹ)
Mo ni ṣo ma pade mi to ba ti dalẹ (′ba ti dalẹ)
Ṣebi awọn paddie mi ni "ko ma lọ bẹ" (Ko ma lọ bẹ)
Jọ, ṣo ma wa pẹlu mi, ba mi kalẹ (Ba mi kalẹ)
Iyi atọla ni mo wa lọ, ah (Wa lọ)
Mo ti rire, mo rayọ (Rayọ)
Gbẹdu gbe de, Kuramo (′Ramo)
Na lie, t'ọn ba l′awọn o damọ (Damọ)
Ki lo fẹ fa karamọ? (Karamọ)
Wọn l'awọn o mọ-ọnmọ (O mọ-ọnmọ)
Wọn jọla Muhammād
O ya give dem, jẹ ki wọn ma sọhun t'ọn sọ
Baby, don′t leave me now
Dakun, ma da mi, jọ
You know me sharp shooter, I'll give you proper now
Sweetie love, my dear oh
You know say me no there oh
Iwọ lo le gbe mi de'bẹ oh
Pretty love, my dear-eh
Girl, you be my super charger
Say if dem try, ọmọ, na back to sender
Mmm, baby, make we meet for zanga
You know say me and Ballo′ give them bangers
Ọmọ, baby, ma jẹ ka ja
I go dey give am to you faster-faster
Baby-baby, ma jẹ ka ja oh
I go dey give am to you faster-faster
So, make we link up, link up, link up
Shayo, drink up, drink up, drink up
Ọmọ, mo ya gbọna ti mi mọ (Ti mi mọ)
If sapa dey, I mọ pe o ni ba mi lọ (O ni ba mi lọ)
Name any hustler, dey for Babylon (For Babylon)
If I no make am, ta lo fẹ ba mi gbọ (Fẹ ba mi gbọ)
Mm, ṣo ma jẹ ki n mọ bo dẹ ṣe ma jẹ (Ṣe ma jẹ)
Mo ni ṣo ma pade mi to ba ti dalẹ (′ba ti dalẹ)
Ṣebi awọn paddie mi ni "ko ma lọ bẹ" (Ko ma lọ bẹ)
Jọ, ṣo ma wa pẹlu mi, ba mi kalẹ? (Ba mi kalẹ)
Iyi atọla ni mo wa lọ, ah (Wa lọ)
Mo ti rire, mo rayọ (Rayọ)
Gbẹdu gbe de, Kuramo (′Ramo)
Na lie, t'ọn ba l′awọn o damọ (Damọ)
Ki lo fẹ fa karamọ (Karamọ)
Wọn l'awọn o mọ-ọnmọ (O mọ-ọnmọ)
Wọn jọla Muhammād
O ya give dem, jẹ ki wọn ma sọhun t'ọn so
Burst my speaker, gimme your knicker
All on me dancer, or in my nice car
Gimme your knicker, whines 'pon ni star
Only me, dies-ah, bicyclely style
Gimme distance, don′t let me distant
All of my guys are, pornstar, my nigga
Mo ti rire, mo rayọ
Mmmm, ọla ni mo wa lọ
Mo ti rire, mo rayọ
Mo rayọ, yeah-yeah
A onile, to salọ
Aroye ko kagbọn
A onile, to
Ecouter
A Propos de "Morayo"
Plus de Lyrics de BALLORANKING
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl