
Wasiu Ayinde Lyrics
...
Wasiu Ayinde Lyrics by BHADBOI OML
Ọmọge wa jo
Ọmọge wa jo
Ọmọge wa jo
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Sure mọ jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Bẹrẹ ko jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Good morning my neighbor
Welcome to wacko season
Bottega Venetta
Na undertaker season
Ija awọn alfa
Pẹlu awọn yellow
L'ọn ba ni k'ọn salamọ
L'ọn ba ṣa Williams
Elo l'ọn ta Lambo
Mo tun fẹ ra condo
Amọkẹ to mọ Porsche
Eh e filẹ, ẹ jẹ o jo
To fi lọkọ ẹnikan
Oun lale ẹnikan
Mo wa lagbo Wasiu Ayinde
Lulu mi bi Wasiu Ayinde
Mo le jo bi Wasiu Ayinde
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Sure mọ jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Bẹrẹ ko jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Elo l'ọn ta Lambo
Mo tun fẹ ra condo
Amọkẹ to mọ Porsche
Eh e filẹ, ẹ jẹ o jo
To fi lọkọ ẹnikan
Oun lale ẹnikan
Mo wa lagbo Wasiu Ayinde
Lulu mi bi Wasiu Ayinde
Mo le jo bi Wasiu Ayinde
Eh wa jo talaso Wasẹ (Ọmọge wa jo)
Watch Video
About Wasiu Ayinde
More BHADBOI OML Lyrics
Comments ( 0 )
No Comment yet
You May also Like
Get Afrika Lyrics Mobile App
About AfrikaLyrics
Follow Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl