
Eleduwa Lyrics
...
Eleduwa Lyrics by BARRY JHAY
Ijọ buruku lo n'ijọ tuntun
Baba, ṣo n gbọ oun aiye nsọ
Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nnkan
Kẹ to d'aiye at'ọrun
And that why me I put you first
In everything I do
Oh mama ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ
Ibi tọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi tọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
Ngba tọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yi ṣe oun rere
Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ'aṣẹ pa
I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o
Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o
T'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu
Ay, ti n ba lu n ṣe ni ko ma dun
Ibi tọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi tọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca
Ngba tọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yi ṣe oun rere
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yi ṣe oun rere
Watch Video
About Eleduwa
More BARRY JHAY Lyrics
Comments ( 0 )
No Comment yet
You May also Like
Get Afrika Lyrics Mobile App
About AfrikaLyrics
Follow Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl