TOPE ALABI Nigbati Mo Ro cover image

Nigbati Mo Ro Lyrics

Nigbati Mo Ro Lyrics by TOPE ALABI


Lati inu oyun
Titi di omo owo o
Igba mo wa lomo owo
Awon ota gba wipe iku o pa mi
Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakawe

Lati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba o
igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
Mo wa ri pe o oga o pupo
igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ogun ti eniyan ja n'agba, o poju Ogun ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko
Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo ooo
Oju ogun laye je feni to waye o wa se rere
Mo wa ronu jinle
Aanu re lori aye mi
Emi ri pe o ga o, pupo
Igba ti mi ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mo ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
Iya to je mi, o je ko je mi gbe o, baba o seun.
A pe omo lowo eyin
Oluso agun fun mi
Olorun iwo ni
Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo
O gbe mi so ke gogoro, Osuba re o baba
Eyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbe
Igba ti mi ro ife nla re Lori mi
Mori pe oga, more ri pe o ga
Mo ri pe o ga Baba.

Igba ti mo ro ife nla re lori mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, more ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Olorun to ga owa loke
Olorun to be ninu aye
Okere titi, ogba mimo eniyan
Owa lotun wa, owa lo si wa
Ayika wa gbogbo, owa ni be
Ohun ni olorun, afeti lu Kara
Larin alawo dudu o n sise e lo
Eyin re eniyan, mo rin ise re
Alawo funfun won teriba fun
Alayi mo n kon, won beere wipe
Tani olorun, ta lolorun
Ayanfe ema da won lo wun pe
Ibi gbogbo lo wa eh
Olorun agbaye

Ibi gbogbo lo wa eh
Ani ko si ibiti oju olorun ko to
Ibi gbogbo lo wa
Olorun nla apejuba, arayerorun

Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lolorun gbe
Ibi gbogbo lo wa
O nbe laye, emi awon woli to to
Ibi gbogbo lo wa
Oro gbe inu omo eniyan fo mu
Ibi gbogbo lo wa
Oti saju aye de, omo inu aye ati eyin aye

Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa olodumare
Ibi gbogbo lo wa
O nbe larin awon angeli mimo
Ibi gbogbo lo wa
Ko si ibiti e pe olorun si ti o wa oh

Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa baba oh
Ibi gbogbo lo wa
Olorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa baba
Ibi gbogbo lo wa
O nbe lokan re ti o ba gba laye

Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo, ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa

Watch Video

About Nigbati Mo Ro

Album : Angeli Mi (Album)
Release Year : 2017
Added By : Preslie Nzobou
Published : Feb 19 , 2020

More TOPE ALABI Lyrics

TOPE ALABI

Comments ( 0 )

No Comment yet



About AfrikaLyrics

Afrika Lyrics is the most diverse collection of African song lyrics and translations. Afrika Lyrics provides music lyrics from over 30 African countries and lyrics translations from over 10 African Languages into English and French

Follow Afrika Lyrics

© 2025, We Tell Africa Group Sarl