
Paroles de Amapiapala
...
Paroles de Amapiapala Par Rybeena
Mo gbe kelebe wọ club o mu Bellaire
La ba dele tan lo ba l'ọn ṣepo o
To ba jerekere stop mi o ba e fẹyin
Sare fun mi lori ọmọ time dey go
Don't please my heart, please my body
Ṣo mọ pọlọmọge yapa nigboro
I no fit lose my feeling for the Benjamin
You no fit enter me
Ṣo mọ iru nigga mi
Ọmọ ko sija ni church ṣadura ki n ṣami
Ọmọ ọpẹ no fit give up ko ṣa ti ri lappy
Ṣebi ọrẹ nigga mi kan lo fi colo yi baki
Lo ba tun kigbe gba mi, gba mi oo
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Ṣo mọ iru nigga mi
Ọmọ ko sija ni church ṣadura ki n ṣami
Ọmọ ọpẹ no fit give up ko ṣa ti ri lappy
Ṣebi ọrẹ nigga mi kan lo fi colo yi baki
Lo ba tun kigbe gba mi, gba mi oo
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Ẹ wa wo ole
Ajibole
O ni ko ki n ṣole
O ri lo gbe
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Iṣo, Baba Ruka
Eyin lo yọ, ẹmi o bọ
Ecouter
A Propos de "Amapiapala"
Plus de Lyrics de Rybeena
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl