...

Paroles de Indika Par OLAMIDE


It's time to put the beam on 'em

Rise and grind by any means on 'em

International funds, I'm overseas on 'em

This is a breath of fresh air

I put the breeze on 'em (Yeah)

Stepping on over this line, there's no borders

Can't have closed minds on these open waters (Sheesh)

Whatever she on, I can afford it

You know I love it when my flavors come assorted

Connoisseur fasho whit something gorgeous

Life is all about these types of moments

And we still in here working just like the rent due

SPINALL, no doubt on the instrumental

Jammin

Hey

Top boy

We bad and critical (Ọlọrun)

To fi de Santa Monica (Ọlọrun)

Money na the ginger (Ọlọrun)

Abeg you make you call my manager (Ọlọrun)

Iya n ronu ọmọ n roka

An faṣẹ wọn fa indika

Ti o ba ṣọra ẹ

O ma kan idin ninu iyọ

Hey

Casablanca, Sacramento

Gbeṣẹ wọle bi ti, Wells Fargo

Ọmọ ọlọpẹ lon ṣọpẹ ba mi ki Marco

Fẹmi Posh, Femi Peckha, mol ẹnu banko

Wọn wa mi Cali de Monaco

Wọn jẹrukọ mi lẹnu, wọn fi fọnu bi pako

Back off, sọ fun awọn nigga make dem back off

Ti n ba spark up awọn goons mi o ni mask up

O taramera o tọ pinpin

Shout out Tunde Perry o lemi o milẹ titi

Ọmọ Yoruba ka jẹba ka dẹ jewedu

Get the money, let the money long, yeah that's how we do

Ori olori ni daddy wọn yalo

Ọgbẹni emi o gbadun o

Awa to kuro n yaro

Lati abẹ igi mango l'Ekoo faṣẹ de Tobago

Strapped up cause inu jin inu narrow

Aye mi bi narcos

Wọkọ ninu cargo

Nigaa nigga Pablo

Abẹtẹ to a smart home

Wake up

Ecouter

A Propos de "Indika"

Album : (Single)
Année de Sortie : 2025
Copyright : © 2025 YBNL Nation / EMPIRE
Ajouté par : Farida
Published : Jun 22 , 2025

Plus de Lyrics de OLAMIDE

OLAMIDE
OLAMIDE
OLAMIDE

Commentaires ( 0 )

Aucun commentaire pour l'instant



A propos de AfrikaLyrics

Afrika Lyrics est la plus large collection de paroles de chansons et de traductions d’Afrique. Afrika Lyrics fournit les paroles des musiques de plus de 30 pays africains et des traductions de lyrics de plus de 10 langues africaines en français et en anglais.

Suivre Afrika Lyrics

© 2025, We Tell Africa Group Sarl