NSNS Agba Picker cover image

Paroles de Agba Picker

Paroles de Agba Picker Par NSNS


You no show love o ( àgbà picker )
Set àwọn ṣawó ṣawó (àgbà picker )
Nigerian limited (àgbà picker )
Wetin be exchange rate ( àgbà picker )
You no show love o ( agba picker )
Set àwọn ṣawó ṣawó  (àgbà picker )
Nigerian limited (àgbà picker )
Wetin be exchange rate ( àgbà picker )

Àgbà picker
Àgbà picker
Àgbà picker
Àgbà picker
Àgbà picker
Àgbà picker

Based on assumption wizzy ni client
Portable lọmọ science
Kògbadídí má hùwà bí ìkà
Exchange ló sọ poco di ripper
Coyate la punte my neighbour ma ja le ka ko bi o ge
Yekele wọlé bí lacoste
Mugabe yàtọ̀si kintakunte
Wọ́n fi jẹ ọbẹ̀ ture ṣàwúre
Ṣo fẹ́ ju Ọlọ́run lọ ni alayé
Owó ye lọ fẹjọ́ mi sun alayé
Ẹ lè ṣe yẹ̀yẹ́ mi lójú aráyé
I don’t care  who's hot who's not
We don’t care who sell out the shows
As a street boy àwa kan wá jagbà left and right
Àwa ò báayím lé bus
Fiílẹ̀

You no show love o ( àgbà picker )
Set àwọn shawo aṣẹ́wó (àgbà picker )
Nigerian limited (àgbà picker )
Wetin be exchange rate ( àgbà picker )
You no show love o ( àgbà picker )
Set àwọn ṣawó ṣawó (àgbà picker )
Nigerian limited (àgbà picker )
Wetin be exchange rate ( àgbà picker )

Wọ́n fẹ́  profile Obagoal
Baddo oòṣà
Lamborita
Àrẹ̀mọ Gucci gafi mane
Elvis multi dollar
Chris the bill  oshe baby
Bishop Ọ̀túnba cash
Istanbul  general one
Obama àbúrò Ibe
Sam Larry o le Cuban
O mọ Larry Wofa
Obi 606
Fẹ́mi  Jagwa olumba
Shina pepper mr white

Ecouter

A Propos de "Agba Picker"

Album : Agba Picker (Single)
Année de Sortie : 2022
Copyright : 2022, No Struggle No Sucess Enterntainment
Ajouté par : Regee
Published : Jan 24 , 2022

Plus de Lyrics de NSNS

Commentaires ( 0 )

Aucun commentaire pour l'instant



A propos de AfrikaLyrics

Afrika Lyrics est la plus large collection de paroles de chansons et de traductions d’Afrique. Afrika Lyrics fournit les paroles des musiques de plus de 30 pays africains et des traductions de lyrics de plus de 10 langues africaines en français et en anglais.

Suivre Afrika Lyrics

© 2025, We Tell Africa Group Sarl