BRYMO Okùnrin Méta (Edun Okàn) cover image

Paroles de Okùnrin Méta (Edun Okàn)

Paroles de Okùnrin Méta (Edun Okàn) Par BRYMO


Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Emi ni imole
Olukunkun wo gbo lo
Mo fa lewuya
Mo te lorun pa
Eniyan lasan mi o je
Mo wiwo bi ésan
Emi ni iji to ja lodo
To gboba won lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Okunrin meta debi ti mo n lo

Ecouter

A Propos de "Okùnrin Méta (Edun Okàn)"

Album : Èsan (Album)
Année de Sortie : 2021
Ajouté par : Farida
Published : Sep 21 , 2021

Plus de Lyrics de BRYMO

BRYMO
Oga
BRYMO
BRYMO

Commentaires ( 0 )

Aucun commentaire pour l'instant



A propos de AfrikaLyrics

Afrika Lyrics est la plus large collection de paroles de chansons et de traductions d’Afrique. Afrika Lyrics fournit les paroles des musiques de plus de 30 pays africains et des traductions de lyrics de plus de 10 langues africaines en français et en anglais.

Suivre Afrika Lyrics

© 2024, We Tell Africa Group Sarl