
Paroles de A Beautiful Song
...
Paroles de A Beautiful Song Par Ayo Maff
Oniyoungi oo
Iwo ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
I wrote you a love song, Orimolade
Ah, joromi ṣo ri ibi ta ba de
I go be your Young John my aquafina
Mo ti salọ fun Sarafina
Your love is a movie, I be Yemi Sholade
Ọmọ, mo le sọnu if you no go follow me
Duro de mi lọna ọja, igba wo lo ma de?
Ọmọ, mo le sọnu if you no go follow me
Igbalode, baby, mo fẹ ko ni nice night
Igbalode, baby mo fẹ ko ni nice night
Iwọ nikan Ololade mi mo ba rode
Iwọ nikan Ololade mi mo ba rode
O ya o ooo
O ya o ooo
Iwọ ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
Mo wa inu tubu
Mi o le jade
If love is a crime, mo wa inu tubu
Oh, I'm in chains, mi o le sare
Your love is a crime, mo wa inu tubu
Normally, I be ọmọ oro, I no be lover boy
Ki n to pade Joromi, I be ọmọ oro
I be gangster, I no be lover boy
Ki n to pade joromi, I be ọmọ oro
I go feel alright to ba gbe mi saya rẹ
Olomi, kọju sọkọ ṣo mọ
I go see more light, iwọ ṣa ni NEPA mi
But olomi, sọ mi sokunkun ọwọ
And I did notice some other things
If you mix Red Bull and Remi Martins
It makes me hyperactive, I dey jogodo
Wa ri mi lọla, Joromi ma ba mi ja
Igbalode, baby, mo fẹ ko ni nice night
Igbalode, baby mo fẹ ko ni nice night
Iwọ nikan Ololade mi mo ba rode
I go see more light, iwọ ṣa ni NEPA mi
O ya o ooo
O ya o ooo
Iwọ ṣa ni ọkan mi yan
Iwọ nikan ṣa ni ọkan mi yan
Ecouter
A Propos de "A Beautiful Song"
Plus de Lyrics de Ayo Maff
Commentaires ( 0 )
Aucun commentaire pour l'instant
Vous aimeriez sûrement
Essayez l'application Mobile
A propos de AfrikaLyrics
Suivre Afrika Lyrics
© 2025, We Tell Africa Group Sarl